ìwògbè

noun
ì-wò-gbè | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of ìwògbè 

1 : Oun tí a máa ń lò láti wo àwòrán ara ẹni.: Mo ra ìwògbè kan.

English Translation

A mirror.

Morphology

ì-wò-gbè

Gloss

- an item, an act

wò - to look (at)

gbè - to support.

Variants

  • Dígí
  • Jígí

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 03 Dec 2019

Most Popular