òǹkọ̀wé

noun
ò-ǹ-kọ̀-wé | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of òǹkọ̀wé 

1 : Ẹni tí ó ń kọ ìwé gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́.: Ọ̀jọ̀gbọ́n Ònkọ̀wé ni Adébáyọ̀ Fálétí kí wọ́n tó di olóògbé.

English Translation

One who writes (professionally). A writer.

Morphology

ò-ǹ-kọ-ìwé

Gloss

- the person who does (something)

- continuity.

kọ - write

ìwé - book

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 18 Nov 2019

Most Popular