àtẹlẹsẹ̀

Noun
à-tẹ-lẹ-sẹ̀ | | GENERAL |

Definition of àtẹlẹsẹ̀ 

1 : Èyí ni abẹ́ ẹsẹ̀ gangan tí a má ń dà délẹ̀.: sole f.a.: Ẹ̀gún gún Gbénró ní àtẹlẹsẹ̀. Thorn pierced Gbenro's sole.

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 11, 2026 and Submitted on November 10, 2026