ègún

Noun
ẹ̀-gún | èɡṹ | GENERAL |

Definition of ègún 

1 : Àìsàn tàbí ìṣòro àtọwọ́dọ́wọ́ nínú ìdílé tí a gbà gbọ́ pé ó wá látàrí èpè àtijọ́ tàbí ìwà àìtọ́ àwọn baba-ńlá. :: a curse f.a.: Ọ̀pọ̀ àbíkẹ́yìn ń bèèrè pé ṣé ègún ni láti jẹ́ àbíkẹ́yìn? Some lastborns do ask if it's a curse to be one.

2 : Ohun mímú tàbí nǹkan tí ó ṣóńṣó lórí igi, ewéko, tàbí egungun ẹja tí ó lè gún ni lára, fà ni ya, tàbí fa ìrora; ẹ̀gún.: A thorn, spine, splinter, or sharp piercing object f.a.: Ègún igi ọ̀pẹ náà gún mi lẹ́sẹ̀ nígbà tí mo ń rìn lóko láìwọ bàtà. The thorn from the palm tree pierced my foot while I was walking on the farm barefoot.

Morphology

è-gún

Gloss

è - nominalizing prefix used to turn actions/verbs into concrete or abstract nouns.

gún - pierce

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 23, 2026 and Submitted on November 16, 2026