ìdajì

Noun
ì-da-jì | ìdad͡ʒì | GENERAL |

Definition of ìdajì 

1 : pípín nǹkan sí ọ̀nà méjì rẹ́gí; ìpín kan nínú ọ̀nà méjì tó pé.: half,.midpoint f.a.: Ó pín búrẹ́dì náà ní ìdajì fún mi kó tó jẹ tiẹ̀ He split the bread in half for me before eating his portion. f.a.: A kì í bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ agbára láti fi ìdajì rẹ̀ ṣòfò. One does not engage in heavy energy-consuming labour only to waste half of its output.

Morphology

ì-dá-méjì

Gloss

ì - the act of

dá - break

méjì - two

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 12, 2026 and Submitted on November 09, 2026