1 : Ẹ̀rọ ìgbàlódé tí wọ́n máa ń kó ẹyin adìyẹ sí tó máa ń sọ ẹyin di ọmọ adìyẹ kẹ́kèèké: Incubator
2 : Ẹ̀rọ-ìpẹyin ti mú kí adìyẹ ṣínṣìn ó di ìrọ̀rùn nítorí pé ó máa ń pèṣè ọmọ adìyẹ lọ́pọ̀ yanturu.: Incubator has made chicken rearing easy because it used to produce day-old chicken in a large quantity.
Most Popular