ẹ̀rọ-amúlétutù

Noun
ẹ̀-rọ-a-mú-lé-tu-tù | | GENERAL |

Definition of ẹ̀rọ-amúlétutù 

1 : Eléyìí ni ẹ̀rọ tó máa ń fẹ́ atẹ́gùn sínú ilé láti fi tutù nítorí ooru.: Air condition f.a.: Mo fẹ́ràn láti máa sùn sínú yàrá tó bá ní ẹ̀rọ-amúlétutù nínú. I love to sleep inside room that has air condition.

Morphology

ẹ̀rọ-amú-ilé-tutù

Gloss

ẹ̀rọ - machine, device, technology

amú - that make

ilé - house, home

tutù - cold

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 06, 2026 and Submitted on November 05, 2026