1 : Ẹni tí ó wà ní agbede ààrin jíjẹ́ ọmọdé àti àgbà tí ó sì ń ní ìdàgbàsókè lọ́kàn àti lára.: youth f.a.: Àwọn ọ̀dọ́ wa ò ríṣẹ́ ṣe ní orílẹ̀-èdè yìí nítorí gbogbo nǹkan ló ti dorí kodò. Our youths in this country are unemployed because things have turned upside down.
Most Popular