Àdéhùn

noun
à-dé-hùn | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of Àdéhùn 

1 : Ohun tí èèyàn méjì tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ fi ẹnu kò sí láti ṣe.: Má gbàgbé àdéhùn wa.

English Translation

A decision agreed upon by two or three people on an action.

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 03 Dec 2019 and Submitted on 21 Nov 2019

Most Popular