Gbéwiri

Noun
gbé-wi-ri | \ \ | GENERAL |

Definition of Gbéwiri 

1 : Ẹni tó ń jalè, pàápàá ẹni tó le gbé nǹkan oníǹkan tí ẹni tó nií kò ní mọ̀.: Thief, robber.

Morphology

gbé-wiri

Gloss

gbé - carry

wiri - in silence, clandestinely

Variants

  • Olè GENERAL
  • Olọ́ṣà GENERAL

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on October 22, 2026 and Submitted on October 22, 2026