àbámọ̀

Noun
à-bá-mọ̀ | àbámɔ̀ | GENERAL |

Definition of àbámọ̀ 

1 : Ìmọ̀lára ìbànújẹ́ ati ẹ̀dùn ọkàn tí ènìyàn ní nígbà tí ó bá ronú nípa ohun tí ó ti ṣe ní ọ̀nà àìtọ́ tàbí ìpinnu tí ó ti ṣe ti ko yọrí bí ẹni náà se lérò: Regret; Remorse f.a.: Òsẹ́ ni ńsíwájú ẹkún; àbámọ̀ ni ńgbẹ̀hìn òràn; gbogbo àgbà ìlú pé jọ, wọ́n ò rí ògùn àbámọ̀ ṣe Hissing comes before weeping; regret comes after a misfortune. All the elders in the town gathered, but none could find a remedy for regret.

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 25, 2026 and Submitted on November 25, 2026