aṣẹ́gun

Noun
a-ṣẹ́-gun | àʃɛ́ɡũ̀ | GENERAL |

Definition of aṣẹ́gun 

1 : Èyí ni ẹni tí ó borí ẹnìkan tàbí ohun kan.: One who conquers someone or something f.a.: Aṣẹgun àti ajogún ní a jẹ́. We are the conqueror and heir.

Morphology

a-ṣẹ́-ogun

Gloss

a - one who

ṣẹ́ - to conquer

ogun - war, battle

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 11, 2026 and Submitted on November 05, 2026