abaraméjì

Noun
a-ba-ra-mé-jì | abaɾaméd͡ʒì | GENERAL |

Definition of abaraméjì 

1 : Ẹni ti awon eeyan gbagbo wipe ó wà láàyè níbi meji ọ̀tọ̀tọ̀ sùgbọ́n ní àkókò kan náà, tí ó sì lè farahàn ní ìrísí ènìyàn ní àwọn ibi méjèèjì..: Reincarnated person f.a.: Ìtàn àbaraméjì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìgbàgbọ́ àṣà ìbílẹ̀ Yorùbá. The story of abaraméjì is one of the beliefs in traditional Yoruba culture.

Morphology

a-bi-ara-méjì

Gloss

a - one who

bi - possess

ara - body, bodies

méjì - two

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 25, 2026 and Submitted on November 25, 2026