1: orúkọ àpèjẹ́ fún ẹni tó ń ṣe éré-ìdárayá ẹ̀ṣẹ́ kíkàn:
Boxer
f.a.:Gbajugbaja abẹ̀ṣẹ́kùbíòjò ni Anthony Joshua
Anthony Joshua is a renowned boxer
Morphology
a-bi-ẹ̀ṣẹ́-kù-bí-òjò
Gloss
a - one who
bi - delivers
ẹ̀ṣẹ́ - blows
kù - bellow
bí - like, as if
òjò - rain
What Do You Think About This Word?
How could we have illustrated it better?
Updated on November 11, 2026
and
Submitted on November 02, 2026