1 : Ẹni tí a yàn láti bá ọba ikú nígbà tí ọba bá kú, ẹni yìí máa ń ní àǹfààní àti ipò ọlá pàtàkì ní ààfin ní gbogbo ìgbà tí ọba bá wà láàyè, ṣùgbọ́n ó gbudọ̀ setán àti kú tẹ̀lé Ọba.: Royal companion destined to die with the king; designated royal attendant. f.a.: Ẹmi ò lè ṣe Abọ́bakú obìnrin. I will not sacrifice my life for a woman.
Most Popular