adigunjalè

Noun
a-di-gun-ja-lè | adiɡũɟalɛ̀ | GENERAL |

Definition of adigunjalè 

1 : Ẹni tó ń fi oun ìjà olóró gba nǹkan lọ́wọ́ọ ẹlòmíràn: armed robber f.a.: Àwọn adigunjalè kọlu ilé ìfowópamọ́. Armed robbers attacked the bank today.

Morphology

a-di-ogun-jalè

Gloss

a - one who

di - to pack, to equip

ogun - arms, war

jalè - to steal

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 11, 2026 and Submitted on November 01, 2026