agbọ̀n

Noun
a-gbọ̀n | aɡ͡bɔ̀n | GENERAL |

Definition of agbọ̀n 

1 : Ohun èlò tí a fi imọ̀-ọ̀pẹ hun láti fi kó, gbé, tàbí tọ́jú onírúurú nǹkan: Wooven Basket f.a.: Àgbọ̀n náà kún fún èso. The basket is full of fruits

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 16, 2026 and Submitted on November 16, 2026