ajílẹ̀

Noun
a-jí-lẹ̀ | ad͡ʒílɛ̀ | GENERAL |

Definition of ajílẹ̀ 

1 : Ohun èlò tí a ń fi sínú ilẹ̀ tàbí sórí ilẹ̀ láti mú kí ilẹ̀ náà ní àwọn èròjà aṣaralóore tí ewéko nílò fún ìdàgbàsókè àti láti mú kí èrè oko pọ̀ sí i.: fertilizer f.a.: Àìlo ajílẹ̀ lè ní ipa lórí ìdàgbàsókè àwọn ohun ọ̀gbìn. Not using fertilizer can affect crop growth.

Morphology

a-jí-ilẹ̀

Gloss

a - one who

jí - wake up, arise

ilẹ̀ - ground, floor

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 23, 2026 and Submitted on November 23, 2026