1: Ẹni tó ń gba ẹ̀kọ́ lọ́wọ́ olùkọ́ tabi ní ilé-ẹ̀kọ́, tó ń wa ìmọ̀ láti lè di ọlọgbọ́n:
student, learner, pupil
f.a.:Akẹ́kọ̌ mẹ́wàá ló wà nínú kíláàsì náà.
There are ten students in that classroom.
Morphology
a-kọ́-ẹ̀kọ́
Gloss
a - one who
kọ́ - learns, to teach, build
ẹ̀kọ́ - education, knowledge, lesson
What Do You Think About This Word?
How could we have illustrated it better?
Updated on November 08, 2026
and
Submitted on November 08, 2026