akẹ́kọ̌

Noun
a-kẹ́-kọ̌ | akɛ́kɔ̀ː | GENERAL |

Definition of akẹ́kọ̌ 

1 : Ẹni tó ń gba ẹ̀kọ́ lọ́wọ́ olùkọ́ tabi ní ilé-ẹ̀kọ́, tó ń wa ìmọ̀ láti lè di ọlọgbọ́n: student, learner, pupil f.a.: Akẹ́kọ̌ mẹ́wàá ló wà nínú kíláàsì náà. There are ten students in that classroom.

Morphology

a-kọ́-ẹ̀kọ́

Gloss

a - one who

kọ́ - learns, to teach, build

ẹ̀kọ́ - education, knowledge, lesson

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 08, 2026 and Submitted on November 08, 2026