aláṣẹ

Noun
a-lá-ṣẹ | | GENERAL |

Definition of aláṣẹ 

1 : Ẹni tó ní agbára láti darí, tí ohun tí ó bá sọ tàbí ṣe jẹ́ ohun tí abẹ gé.: ruler, commander f.a.: Ìyá onílẹ̀kẹ̀ ni aláṣẹ fún gbogbo àwọn Obìnrin tó ń ta ọjà lọ́jà Ayétòrò. The woman that sells bead is the commander for all market women at Ayetoro market.

Morphology

oní-àṣẹ

Gloss

oní - one with

àṣẹ - authority

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 15, 2026 and Submitted on November 15, 2026