alátẹ

Noun
a-lá-tẹ | | GENERAL |

Definition of alátẹ 

1 : Ẹni tó ń ta ọjà ohun jìjẹ fún àwọn aláràtúntà tàbí àwọn tó máa lǒ.: Petty trader f.a.: Àwọn ọ̀rẹ́ mẹ́rin tan ọmọ alátẹ lọ sílé àkọ́kù, wọ́n gbowó ọwọ́ rẹ̀, Four friends lured the petty trader into an uncompleted building and took his/her money.

Morphology

oní-àtẹ

Gloss

oní - owner of, seller of

àtẹ - platform (for selling)

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 19, 2026 and Submitted on November 16, 2026