1 : Ìwà jíjẹ́ kí ìnáwó máa bíni nínú; tàbí ninawo pelu ìkùnsínú nígbà gbogbo tí a bá fẹ́ ná owó: parsimony, reluctance to spend f.a.: Àróró kò jẹ́ kí ó ra ohun tó nílò. His reluctance to spend prevents him from buying what he needs.
Most Popular