aròró

Noun
a-rò-ró | aróró | GENERAL |

Definition of aròró 

1 : Ìwà jíjẹ́ kí ìnáwó máa bíni nínú; tàbí ninawo pelu ìkùnsínú nígbà gbogbo tí a bá fẹ́ ná owó: parsimony, reluctance to spend f.a.: Àróró kò jẹ́ kí ó ra ohun tó nílò. His reluctance to spend prevents him from buying what he needs.

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 12, 2026 and Submitted on November 12, 2026