àpérò

Noun
à-pé-rò | àpérò | GENERAL |

Definition of àpérò 

1 : Ìpàdé àwọn ènìyàn láti jíròrò.: Conference of people to discuss. f.a.: Ààrẹ orílẹ̀ èdè pe àpérò fún gbogbo ẹ̀yà. The President of the country called a Conference for all tribes.

Morphology

a-pe-èrò

Gloss

a - PREFIX (agent)

pe - call

èrò - crowd

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 12, 2026 and Submitted on November 03, 2026