1: Ẹni tá a fi sínú àtìmọ́lé tàbí tí ìjọba ti fi sí àhámọ́ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ṣẹ̀:
prisoner
f.a.:Ẹlẹ́wọ̀n ò ní òmìnira kankan
A prisoner has no freedom at all
Morphology
oní-ẹ̀wọ̀n
Gloss
oní - one who
ẹ̀wọ̀n - chain, prison
What Do You Think About This Word?
How could we have illustrated it better?
Updated on November 08, 2026
and
Submitted on November 05, 2026