1 Transitive Láti sọdá láti ẹ̀gbẹ́ ibì kan sí ẹ̀gbẹ́ kejì to cross f.a.: Wo ọ̀tún àti òsì dáadáa kí o tó fọ̀nà. Look carefully to your right and left before crossing the road. f.a.: Ọmọ náà dúró de àkókò tí kò sí ọkọ̀ kí ó tó fọ̀nà. The child waited until there were no vehicles before crossing the road.
Most Popular