1 : Ọkùnrin tàbí ọkọ tí ó jẹ́ òmùgọ̀ pátápátá lábẹ́ ìyàwó rẹ̀, tí kò ní àṣẹ kankan nínú ilé: henpecked husband, f.a.: Gbẹ̀wùdání ni ọkọ ìyálóde Iyalode's husband is a henpaecked husband
2 : Ẹni tí àwọn ẹlòmíràn ń lò bíi nǹkan-ìṣeré láìní òmìnira láti dá ìpinnu ara rẹ̀ ṣe: stooge, dunce
Most Popular