gbégilódò

Noun
gbé-gi-ló-dò | | GENERAL |

Definition of gbégilódò 

1 : Ọkọ̀ ńlá tá a fi ń gbé igi ńlá láti inú igbó lọ sí ibi tí a ó ti lò wọ́n: Timber lorry f.a.: Wọ́n fi gbégílódò gbé àwọn igi tí wọ́n gé lọ. They used a logging truck to transport the felled trees.

Morphology

gbé-igi-ní-odò

Gloss

gbé - carry, to carry

igi - trees

ní - at, in

odò - river

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 16, 2026 and Submitted on November 16, 2026