gègé

Noun
gè-gé | | GENERAL |

Definition of gègé 

1 : Ohun èlò tí a fi ń kọ̀wé tàbí ṣe àmì sórí bébà àti àwọn ohun mìíràn.: pen f.a.: Mo fi gègé kọ orúkọ mi sínú ìwé. I used a pen to write my name in the book.

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 14, 2026 and Submitted on May 24, 2026