ìjọ̀gbọ̀n

noun
ì-jọ̀-gbọ̀n | \ \ | ABEOKUTA |

Definition of ìjọ̀gbọ̀n 

1 : Wàhálà. Hílàhílo.: Ìjọ̀gbọ̀n ẹ ti pọ̀jù.

2 : Oníjọ̀gbọ̀n.: Ìjọ̀gbọ̀n ti dé láti ìrìn àjò.

English Translation

Trouble. A troublemaker.

Morphology

ìjọ̀gbọ̀n

Gloss

ìjọ̀gbọ̀n - trouble, skirmis

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 10 Jun 2018

Most Popular