1: Èyí ni títiraka láti ṣe nǹkan bótilẹ̀ jẹ́ pé ó nira.:
Perseverance
f.a.:Ìrọ́jú ni mo fi pọn omi yẹn ní ìdájí yìí.
I persevered to fetch the water this dawn.
Morphology
ì-rọ́jú
Gloss
ì - something that
rọ́jú - Persevere.
What Do You Think About This Word?
How could we have illustrated it better?
Updated on November 12, 2026
and
Submitted on May 24, 2026