ìtẹ́

Noun
ì-tẹ́ | ìtɛ́ | GENERAL |

Definition of ìtẹ́ 

1 : Àga ìjókòó tí ọba tàbí ọlọ́lá ń jókòó sí láti ṣàkóso ìlú.: Throne f.a.: Ọba jókòó lórí ìtẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú ògo. The king sat on his throne with glory

2 : Ilé tí ẹyẹ́ bá kọ́ pẹ̀lú koríko láti máa gbé tàbí yé ẹyin sí: nest f.a.: Ẹyẹ náà kọ́ ìtẹ́ rẹ̀ sí orí igi gíga. The bird built its nest on top of a tall tree.

Morphology

ìtẹ́

Gloss

ìtẹ́ - nest, throne

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 11, 2026 and Submitted on November 04, 2026