ibi

Noun
i-bi | \ \ | GENERAL |

Definition of ibi 

1 : Ààyè tí èèyàn wà.: A place, location. f.a.: Ibi mélòó lo ti dé ri? How many places have you visited?

2 : Oun tí kò dára. Láburú: Evil f.a.: Tibi tire la dá ilé ayé. Life is full of good and evil.

3 : Ẹ̀yà ara tí ó so ọmọ inú oyún papọ̀ mọ́ ìyá ẹ̀ láti ìdodo.: Umbilical cord. f.a.: Ọmọ tí a bí pẹ̀lú ibi lọ́rùn ni a ń pè ní Òjó. A child born with the umbilical cord around their neck.

Morphology

ibi

Gloss

ibi - place

ibi - evil

ibi - umbilical cord

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on April 26, 2026 and Submitted on February 16, 2026