1 : Ipò tí ohun kan kò bá ń lọ síwájú mọ́, tí ó sì ń padà sí ipò tí kò dára tó ti wà tẹ́lẹ̀. Ó lè jẹ́ àbájáde ìṣòro, ìpinnu tí kò dára, tàbí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó dí ìlọsíwájú lọ́wọ́.: setback, regression f.a.: Àìsí owó tó tó fún ilé-ẹ̀kọ́ náà fa ìfàsẹ́yìn nínú ètò ẹ̀kọ́. Insufficient funding for the school caused a setback in the education system.
Most Popular