ìfẹ̀hónúhàn

Noun
ì-fẹ̀-hó-nú-hàn | | GENERAL |

Definition of ìfẹ̀hónúhàn 

1 : Ìṣe tí àwọn ènìyàn ń fi èrò àìtẹ́lọ́rùn, àtakò tàbí àìgbàgbọ́ wọn hàn nípa ohun kan tí wọ́n kò fara mọ́.: protest f.a.: Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ṣe ìfẹ̀hónúhàn láti tako ìpinnu ìṣàkóso ilé-ẹ̀kọ́ náà. The students staged a protest against the school's management decision.

2 : Ìfẹ̀hónúhàn náà fa àfiyèsí sí ìṣòro àìní omi mímu ní agbègbè náà.: The protest drew attention to the problem of inadequate access to drinking water in the area.

Morphology

ì-fi-ẹ̀hónú-hàn

Gloss

ì - something that, act of

fi - use

ẹ̀hónú - grievances, complaint

hàn - appear, show, display

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 13, 2026 and Submitted on November 13, 2026