1 : Ìmọ̀lára ìbànújẹ́ tàbí àìtẹ́lọ́rùn tí ènìyàn ní nígbà tí ohun tí ó retí kò ṣẹlẹ̀ tàbí tí ìdáwọ́lé rẹ̀ kò yọrí sí rere.: disappointment, failure, setback f.a.: Ìjákulẹ̀ tí ó ní nínú ìdánwò náà kò jẹ́ kí ó jáwọ́ nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀. The disappointment he experienced in the examination did not make him give up on his studies.
Most Popular