1 : Àga ìjókòó tí ọba tàbí ọlọ́lá ń jókòó sí láti ṣàkóso ìlú.: Throne f.a.: Ọba jókòó lórí ìtẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú ògo. The king sat on his throne with glory
2 : Ilé tí ẹyẹ́ bá kọ́ pẹ̀lú koríko láti máa gbé tàbí yé ẹyin sí: nest f.a.: Ẹyẹ náà kọ́ ìtẹ́ rẹ̀ sí orí igi gíga. The bird built its nest on top of a tall tree.
Most Popular