Kan

adjective
kan | \ /k ọn/ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of Kan 

1 : Kí nǹkan rí lẹ́nu dàbíi pé ó ti fẹ́ bàjẹ́, ṣùgbọ́n kò tíì bàjẹ́ tán.: Oúnjẹ yẹn ti kan.

2 : Kí nǹkan mú lẹ́nu bí ọsàn tí kò tíì pọ́n.: Ògì yẹn kan lẹ́nu.

3 : Kí nǹkan dù èèyàn lára.: Ọmọ yẹn ń kan'ra gan.

English Translation

[Of food and taste] Going off. Tangy. Sour. Edgy (in the mouth). Something that brings pain or irritability.

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 03 Dec 2019 and Submitted on 29 Nov 2019

Most Popular