1 : Gbigba eni nimoran nípa ewu, ìṣòro tàbí àbájáde búburú tí ó lè ṣẹlẹ̀, láti jẹ́ kí ẹni náà ṣọ́ ara wọn: to warn, to caution f.a.: Ọlọ́pàá kìlọ̀ fún àwọn awakọ̀ nípa ewu tó wà ní ọ̀nà náà. The police warned drivers about the danger on that road.
Most Popular