ọ̀jọ̀gbọ́n

Noun
ọ̀-jọ̀-gbọ́n | ɔ̀d͡ʒɔ̀ɡ͡bɔ́n | GENERAL |

Definition of ọ̀jọ̀gbọ́n 

1 : Ẹni tó ní ipò ẹ̀kọ́ gíga ní yunifásítì, tí ó sì jẹ́ amòye nínú ẹ̀ka ìmọ̀ kan, tó si ń kọ́ àwọn ẹlòmíràn nínú ìṣẹ́ ìwádìí ṣíṣe.: proffesor, senior academic; learned scholar f.a.: Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló wá sí ìpàdé tí ọ̀jọ̀gbọ́n náà ṣe. Many people attended the meeting organised by the professor.

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 23, 2026 and Submitted on November 23, 2026