òkóbó

Noun
ò-kó-bó | | GENERAL |

Definition of òkóbó 

1 : Ọkùnrin tí kò ní agbára tàbí mímúná láti nìkan gún régé nínú ìbálòpọ̀ pẹ̀lú obìnrin: an impotent man f.a.: Àwọn tí ń ta egbòogi lẹ́bàá ọ̀nà máa ń sọ pé àwọn ní oògùn tó lè wo òkóbó sàn. Traditional medicine sellers by the roadside often claim they have remedies that can cure impotence. f.a.: Ìyà méjì kì í jẹ òkóbó; tí ò bá lókó, á lóko. Two misfortunes must not plague an impotent man; if he lacks sexual virility, he should at least possess a thriving farm.

2 : Ọkùnrin tí a ti tì, tẹ̀ lọ́ dà tàbí sọ dọ̀bàlẹ̀ tí kò le bímọ rárá.: a eunuch, a castrated man f.a.: Òkóbó ò lè fi alátọ̀sí ṣẹ̀sín. A eunuch cannot mock a person suffering from gonorrhoea.

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 15, 2026 and Submitted on November 03, 2026