onígbàjámọ̀

Noun
o-ní-gbà-já-mọ̀ | onĩ́ɡ͡bàd͡ʒámɔ̃̀ | GENERAL |

Definition of onígbàjámọ̀ 

1 : Ẹni tí n fí abẹ fá irun orí àti ṣíṣe ìtọ́jú irun fún àwọn èlomíì: barber f.a.: Kí ni apárí ńwá ní ìsọ̀ onígbàjámọ̀? What is a bald person looking for at a barber's stall?

Morphology

oní-gbàjámọ̀

Gloss

oní - one who

gbàjámọ̀ - barber

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 08, 2026 and Submitted on November 08, 2026