1 : Ojú ibi tí a ṣe pẹ̀lú igi(pákó) tàbí irin tí èèyàn lè kọ tàbí yà ǹkan sí láti júwe tàbí ṣe ìpolówó.: A large surface made from wood or iron where one can write to advertise or guide. f.a.: Ìjọba ń gbowó pátákó ajúwe. The government charges for billboards
Most Popular