1 : Ọ̀nà àtijó tí a fiń wọ aṣọ nípa fífi aṣọ náà kọ́ ara láti abẹ́ apá koja lọ sí orí i èjìká.: To drape a wrapper over the shoulder; To pass a length of cloth from underneath the the arm over the shoulder. f.a.: Àwọn ọkùnrin náà pakájà aṣọ ìbílẹ̀ wọn fún ayẹyẹ náà. The men draped their traditional cloth for the ceremony.
Most Popular