1 Lílọ sí ibi tí ẹlòmíràn wà, tàbí sí ibì kan, fún ìdí kan pàtó. Ó lè jẹ́ fún ìbáṣepọ̀, ìdárayá, iṣẹ́, tàbí ìwádìí. visit, visitation f.a.: Ààrẹ ṣe ìbẹ̀wò sí ilé ìwòsàn náà láti mọ bí àwọn aláìsàn ṣe wà. The president paid a visit to the hospital to find out how the patients were doing.
Most Popular