1 : Ṣíṣàkójọpọ̀ nǹkan tàbí owó papọ̀ lọ́nà àìtọ́ fún pínpín lǎrin àwọn èèyàn kan.: Collusive sharing. f.a.: Àpapínwọ́ jẹ́ ọ̀kan lára ìwà ìbàjẹ́ tí kò jẹ́ kí Nàìjíríà ó dàgbà. Collusive sharing is one of the corrupt practices preventing Nigeria from developing.
Most Popular