àyọjúràn

Noun
à-yọ-jú-ràn | àjɔʤúrã̀ | Colloquial |

Definition of àyọjúràn 

1 Kí ènìyàn máa dásí tàbí ṣe ohun tí kò kan èèyàn. meddling, prying f.a.: Kò yẹ kí o máa ṣe àyọjúràn sí ọ̀rọ̀ ìdílé àwọn ẹlòmíràn. You should not meddle in other people's family affairs.

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 28, 2026 and Submitted on November 16, 2026