1 : Ẹranko kékeré kan tó ní eyín iwájú tó mú, tó sì sábà máa ń gbé nínú ilé, tabi ihò, nínú ihò tàbí ní àwọn ibi tí ó ti lè rí oúnjẹ.: rat f.a.: Àìsí nílé ológìnní, ilé di ilé ẹkúté. hen the cat is away, the house becomes the rat's domain
Most Popular