ètò-adójútòfò

Noun
è-tò-a-dó-jú-tò-fò | | GENERAL |

Definition of ètò-adójútòfò 

1 : Ètò tí àwọn ilé-iṣẹ́ aládǎni tàbí ilé-iṣẹ́ ìjọba máa ń gbé kalẹ̀ láti pèsè dúkíà tí èèyàn tàbí ilé-iṣẹ́ bá pàdánú látàrí ìjàm̀bá tó fẹ̀ ṣẹlẹ̀.: Insurance f.a.: Ìjọba ti pàṣẹ fún gbogbo òṣìṣẹ́ ìjọba láti fi orúkọ sílẹ̀ fún ètò-adójútòfò. Government has mandated it for all government workers to register for insurance.

Morphology

ètò-adá-ojú-ti-òfò

Gloss

ètò - plan

adá - create

ojú - face

ti - to

òfò - lost

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 10, 2026 and Submitted on November 10, 2026